Exodus 10:21
Òkùnkùn bo ilẹ̀
21
Nígbà náà ni
Olúwa
sọ fún Mose pé, “Gbé ọwọ́ rẹ sókè sí ojú ọ̀run kí òkùnkùn bá à le bo gbogbo ilẹ̀ Ejibiti; àní òkùnkùn biribiri.”
Copyright information for
YorBMYO